Monday, 29 September 2014

Ibadan Lyrics by Q-Dot ft. Olamide

Ibadan Lyrics by Q-Dot ft. Olamide

bi sekere ba ti dun oo konga a tele
ijo maa tele
dakun ko’gi le’lu oo fun mi o jare


Verse 1:
lat’eko de challange
a gba guru maraji
a wole pelu bugatti
ankara lori versace
idi n be ni’badan o
oke n be ni’badan o
idi arere, idi ayunre, oke sango, oke mapo
e ma je ko di’ja
oloso yapa ni bodija o
pelu sokoto penpe
awon omo mi ni molete
e ma s’oko f’eye twitter
alomo meta fe ya speaker
furo rabata fe ya bumber
them say them wan to boogie down

Chorus:
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
be wan de’ko be bami n’le
ibadan ni mo re

Ba-badoo
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
be wan de’ko be bami n’le
ibadan ni mo re

Verse 2:
eh shoutout si awon omo uni
lead city dey ibadan poly
e bami ki kunle silencer
omo musulumi to n fa poli
ero ton lo london
e bami ki kayode kida
tirin gbeku tele tele
omo ibadan to di nigga
omo woli ton fa taba
basira su sara ko tamba
omugo fe ha e o gun ladder
won de ni mama re fe area father
ki le tun fe ti ilekun fe kun
o yo tan o n wa bekun bekun
a i turn up tan o shi seku
ka to fi *** odi seven

Chorus:
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
be wan de’ko be bami n’le
ibadan ni mo re

ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
be wan de’ko be bami n’le
ibadan ni mo re

Verse 3:
oya ni ile oluyole o, awon omo la fi ikarahun fo’ko mu
ijo shoki mo gbe wa o no be skelewu
a tan’na wole pelu sanpeni
kini a de temi complaining
owo afefe la fi n sustaining
ti naira ba ti tan, ma ko pounds jade
k’won fun mi lolosho to wo gown
k’won fun mi lorogbo to ti brown
eyin ko le ma so fun wa pe osogbo ti di town
we rocking gucci gucci, a joko so ri sia cushion
eran sikin la gbe hanu jare

Chorus:
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
be wan de’ko be bami n’le
ibadan ni mo re

ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
ibadan ni mo wa o
ibadan ni mo re o
be wan de’ko be bami n’le
ibadan ni mo re

Outro:
Na na na
ikorodu lo ga wa oo
ni ile oluyole omo a fi ikarahun fo’ko mu
Na na na
****
Abiodun olayinka
mr omodele mohmoodu
olamide baddoo
*****
jambaze on the mix, ma jo
Jambaze mix

No comments:

Post a Comment